Songtexte.com Drucklogo

Ask About Me Songtext
von Mohbad

Ask About Me Songtext

Ask about me, ask about me

Wọ′n ti lé mi, but wọ'n ò mú mi
Ọmọ Ọlọrun kò lè ṣù mí
Sekeseke bula
I′m still getting my mulla
Dollar pẹ'lú naira

Iku tó pa iya teacher
Ò le pa àwọn nigga

Kí ló ń fo lókè o (fo lókè)
Eye ló ń fo lókè o (fo lókè)
Kí ló ń rìn nílé (rìn nílé)
Àwọn ẹ'yàn ló máa ń rìn nílé

Matemi molẹ oh (ooh)
Matẹ oju ilé molẹ
Kómàbà dobale
Ìwọ ló máa fẹ"kọ′lé
O ò lè kú lẹ′
One man soldier


Mẹ'tà mẹ′tà gbọ'sa
Awilo Logomba
Fún mi lówó mi biza
Kesekese kasa
Kasakasa Blanca

I open Bible chapter
I step on the Satan
Mo pè′sù danu
Mo kan l'ẹsẹ′ kan
Ọtamurẹ'gẹ' jìgan oh why, ooh why

They don′t know, they don′t know
They don't know, they don′t know
I don go (they donnnnn know)

They wan know, they wan know
They wan know, they wan know
Where I'm going (I don gooooo)
Kí ló fà frapapapa
Kí ló fà pattern yẹn

Wọn fẹ′ ká mi mọ'n ibẹ′yẹn
Ọpọn ti sùn finally
Ọpọn ti sùn finally
A ò b'ẹnu méjì ṣeré mọ'n


Ask about me, ask about me
Wọ′n ti lé mi, but wọ′n ò mú mi
Ọmọ Ọlọrun kò lè ṣù mí
Sekeseke bula
I'm still getting my mulla
Dollar pẹ′lú naira

Iku tó pa iya teacher
Ò le pa àwọn nigga

Kí ló ń fo lókè o (fo lókè)
Eye ló ń fo lókè o (fo lókè)
Kí ló ń rìn nílé (rìn nílé)
Àwọn ẹ'yàn ló máa ń rìn nílé

Matemi molẹ oh (ooh)
Matẹ oju ilé molẹ
Kómàbà dobale
Ìwọ ló máa fẹ"kọ′lé
O ò lè kú lẹ'
One man soldier

Mẹ′tà mẹ'tà gbọ'sa
Awilo Logomba
Fún mi lówó mi biza
Kesekese kasa
Kasakasa Blanca

I open Bible chapter
I step on the Satan
Mo pè′sù danu
Mo kan l′ẹsẹ' kan
Ọtamurẹ′gẹ' jìgan oh why, ooh why

Songtext kommentieren

Log dich ein um einen Eintrag zu schreiben.
Schreibe den ersten Kommentar!

Fans

»Ask About Me« gefällt bisher niemandem.