Songtexte.com Drucklogo

Je'le O Sinmi Songtext
von Brymo

Je'le O Sinmi Songtext

Ní kékeré, a má ńṣeré
À mà ń f′àwọn àgbààgbà ṣeré
À má ńmere
Ìyá Dele, sọ fún Dele
Kò ye fó 'na, kò tó wo ′na, ko to mere

Bọ 'mọdé ńṣeré, kò tó ṣeré délé
Àwọn àgbà-gbà wọn mà ṣé'to were-were
Bọ ′mọdé ńṣíṣẹ, ko tó rí jẹ
Ìtìjú ní fún àwọn àgbà-gbà to rán ní ṣẹ

Jẹ lé o sinmi ooo
Jẹ lé o sinmi
Jẹ k′ọmọdé o kàwé
Kò kẹ'kọ′ jèrè
Jẹ lé o sinmi ooo
Jẹ lé o sinmi
Àwọn àgbà-gbà múra sí ṣẹ were-were


A mà ń ṣeré
À mà ń sáré
À mà ńṣubú, à mà ń dídé, a mà ńdele
Ìyá Taye sọ fún Taye
Kò yé sọrọ, kò to mọ'rọ yeke-yeke

K′ọmọ o to sa ńlé
Ko tó dí pé o ń sáré kírì
Àwọn àgbà-gbà wọn má ṣètò were-were
B'ọmọdé ń ṣíṣẹ, ah, ko to rí jẹ
Ìtìjú ní fún àwọn àgbà-gbà to rán ní ṣẹ

Jẹ lé o sinmi ooo
Jẹ lé o sinmi
Jẹ k′ọmọdé o kàwé
Kò kẹ'kọ' jèrè
Jẹ lé o sinmi o, o sinmi
Àwọn àgbà-gbà múra sí ṣẹ were-were (were-were)

Wure, wure, wure e-

Jẹ lé o sinmi (jẹ lé o sinmi)
Ko sinmi (ko sinmi)
K′ọmọdé o kàwé (k′ọmọdé o kàwé)
Kò jèrè (kò jèrè)
Jẹ lé o sinmi o (jẹ lé o sinmi o)
Ko sinmi (ko sinmi)
Àwọn àgbà-gbà múra sí ṣẹ were-were


Ko sinmi (ko sinmi)
Ani, ko sinmi (ani, ko sinmi)
Ko kà'we (ko kà′we)
Ko jèrè (ko jèrè)
Jẹ lé o sinmi o (jẹ lé o sinmi o)
Ko sinmi (ko sinmi)
Ko, ko sinmi, ko-ko jèrè

Songtext kommentieren

Log dich ein um einen Eintrag zu schreiben.
Schreibe den ersten Kommentar!

Beliebte Songtexte
von Brymo

  1. Ara

Quiz
Wer singt das Lied „Haus am See“?

Fans

»Je'le O Sinmi« gefällt bisher niemandem.