Songtexte.com Drucklogo

Juju Dance Songtext
von Temidayo Balogun

Juju Dance Songtext

Aye wa adara
Igba wa′dara
Asiko yi a san wa o e

Aye wa adara
Igba wa'dara
Asiko yi a san wa o e

Ayé wa á dára
Ìgbà wa á dára
Àsìkò yìí á ṣàn wá o e

Aye wa adara
Igba wa′dara
Asiko yi a san wa o e


Aye wa adara
Igba wa'dara
Asiko yi a san wa o e

Àsìkò yìí á ma ṣàn wá sí re o
Àsìkò yìí á ṣàn wá o e

Ká máa rí jẹ Ká máa rí mu o
Àsìkò yìí á ṣàn wá o e

Ìgbà yìí á ma ṣàn wá sí re o
Ìgbà yìí á ṣàn wá o e

Kí eku ké bí eku, kí ẹyẹ ké bí ẹyẹ
Àsìkò yìí á ṣàn wá o e

Kí ọmọ ènìyàn fọọ wun o

Ìgbà yìí á ṣàn wá o e

Songtext kommentieren

Log dich ein um einen Eintrag zu schreiben.
Schreibe den ersten Kommentar!

Quiz
Wer will in seinem Song aufgeweckt werden?

Fans

»Juju Dance« gefällt bisher niemandem.