Onilenrele Songtext
von Beautiful Nubia and the Roots Renaissance Band
Onilenrele Songtext
Idera de, e jo e yo - ara e wa, e jo, e yo
A k'onile, e ma k'alejo
A k'eni ti ns'eto k'o le da o
Abanise at'awon abaniro
E wa jo, e wa yo, e wa gb'orin t'odun o
A ma gb'ere otun wo'lu o, ni gbedemuke
Pa 'ronu re, e jo, e yo E k'omode e ma k'alagba o
E k'eni ti ngb'ero k'o le da o e
Abanigbe at'awon abanito
So 'tiju nu, e jo, e yo
Gbogbo aye l'a pe ma s'afara
L'agbo n'ibi enikan o ga ju kan lo o e
E gb'emu wa ki baba f'adura si
Iran o ni gbe yin lo o, ijo o ni jo yin o
Iru nkan ayo bayi laa ma ri
Mo wa fe da'rin kan bayi, s'e gbe?
Oba gba mi o, ojo nlo, onilenrele won, gba mi o, ojo nlo o
Olofin orun, adaniwaye, enis'ojuse'mu, eni to ran mi wa,
Adanib'otiri, oba aiku gbanigbani l'ojo ewu
E ma ri se o

Writer(s): olusegun akinlolu Lyrics powered by www.musixmatch.com