Songtexte.com Drucklogo

Olorun Songtext
von Asake

Olorun Songtext

(Ololade mi, Asake)
Èmí mí kọ, Ọlọrun mà ní
Èmí mí kọ, Ọlọrun mà ní
Àwá kọ oh-oh-oh
Èmí mí kọ o, Ọlọrun ma ní

Tá lo gbọn t′Ọlọrun? (Ọmọ ọgbọn)
Kò sí anybody to lọ gbọn t'Ọlọrun
Tí wọn bá buga ẹ, oya gbà f′Ọlọrun
Àwọn tí wọn buga mi, wọn tí sá pá mọ o
Wọn ti sá pá mọ o

Èmí mí kọ o (oh), Ọlọrun mà ní (Ọlọrun mà ní o)
Èmí mí kọ o (oh), Ọlọrun mà ní (Ọlọrun mà ní o)
Àwá kọ oh, Ọlọrun mà ní o
Oh-oh, oh, èmí kọ o, Ọlọrun mà ní o

Ọmọ no be me, ṣebí na God
Carry me from down straight to the top
2020, it was real tough
Fall for ground, almost gave up
Mó fún wọn l'Ọmọ Ọpẹ, mó dẹ jẹ lọ
Go naked in my room and speak to God
Baba God, I no sabi all
So, guide me, as I dey move on on-on

Tá lo gbọn t'Ọlọrun?
Kò sí anybody to lọ gbọn t′Ọlọrun
Tí wọn bá buga ẹ, oya gbà f′Ọlọrun
Àwọn tí wọn buga mi, wọn tí sá pá mọ o
Uhn, wọn ti sá pá mọ o

Èmí mí kọ o (oh), Ọlọrun mà ní (Ọlọrun mà ní o)
Èmí mí kọ o (oh), Ọlọrun mà ní (Ọlọrun mà ní o)
Àwá kọ oh, Ọlọrun mà ní o
Oh-oh, oh, èmí mí kọ o, Ọlọrun ma ní o

Èmí mí kọ o (oh), Ọlọrun mà ní (Ọlọrun mà ní o)
Èmí mí kọ o (oh), Ọlọrun mà ní (Ọlọrun mà ní o)
Àwá kọ oh, Ọlọrun mà ní o
Oh-oh, oh, èmí mí kọ o, Ọlọrun mà ní o

Ńkán-kán o gbọdọ ṣe àwọn ọmọ ológo o
Mímí kàn o gbọdọ mí àwọn ọmọ Ọlọrun o
Alhamdulillah, I'm a brand new man
(Tune in to the king of sounds and blues)

Songtext kommentieren

Log dich ein um einen Eintrag zu schreiben.
Schreibe den ersten Kommentar!

Beliebte Songtexte
von Asake

Fans

»Olorun« gefällt bisher niemandem.