Songtexte.com Drucklogo

Mogbe Songtext
von Asake

Mogbe Songtext

(Ọlọladé mí, Àṣàkẹ′)
(Tune into the king of sound and blues)

Loud kàn (mogbé, mogbé o)
Ṣáyo kàn (mogbé, mogbé o)
Colorado kàn (mogbé o, mogbé o, mo gbé o)
Cannister kàn (mogbé o, mogbé o, mo gbé o)

Mo kù, mo daran (mo gbé)
Ọmọ yí fẹ pamí oh (mo gbé o)
Too much emotions (mo gbé)
Insecurity wàhálà (mo gbé o)
I don't want no yawa (mo gbé o)
Ọrọ ifẹ ní mo bà wá (mogbé o, mogbé o, mogbé o)
Orekelẹwa mí (mogbé o)
You′re my wonderful woman (mogbé o, mogbé o)

I know, I be sharp guy
Chilling by the pool side (pool side)
Bitches on my right side
You're on my left side
In case, you see I'm online, all-all na lifestyle


Make we go on a long ride (long ride)
Me and you together
Let′s stay all night, looking at the star shine
Make love ′til the sun rise, 'til the sun rise, rise-rise-rise-rise

You′re my only woman (ògbólógbó)
My perfect human (human)
You make my world feel so right, even sometimes when I'm wrong
Baby, jẹka lo ′rawa and forget all the trauma
Ìyàwó mí ní ìyàwó mí, Olufunmi, jọ'wọ′

Loud kàn (mogbé, mogbé o)
Ṣáyo kàn (mogbé, mogbé o)
Colorado kàn (mogbé o, mogbé o, mogbé o)
Cannister kàn (mogbé o, mogbé o, mogbé o)

Mo kù, mo daran (mo gbé)
Ọmọ yí fẹ pamí oh (mo gbé o)
Too much emotions (mo gbé)
Insecurity wàhálà (mo gbé o)
I don't want no yawa (mo gbé o)
Ọrọ ifẹ ní mo bà wá (mogbé o, mogbé o, mogbé o)
Orekelẹwa mí (mogbé o)
You're my wonderful woman (mogbé o, mogbé o)


Make I be your gold like Simi (gold like Simi)
Oh my baby, come and see me (come and see me)
Na you be my Bloody Martini
Kò mí jẹ rush-rush, Tetrazzini
Kò yẹ k′oma ṣ′áko sí mí (ṣ'áko sí mí)
Mr. Money, sure person ni (sure person ní)
Every day lo ńgb′ọpẹ fún mí
I'm dope like Coke, ò ro pé Pepsi ní

Loud kàn (mogbé, mogbé o)
Ṣáyo kàn (mogbé, mogbé o)
Colorado kàn (mogbé o, mogbé o, mogbé o)
Cannister kàn (mogbé o, mogbé o, mogbé o)

Mo kù, mo daran (mo gbé)
Ọmọ yí fẹ pamí oh (mo gbé o)
Too much emotions (mo gbé)
Insecurity wàhálà (mo gbé o)
I don′t want no yawa (mo gbé o)
Ọrọ ifẹ ní mo bà wá (mogbé o, mogbé o, mogbé o)
Orekelẹwa mí (mogbé o)
You're my wonderful woman (mogbé o, mogbé o)

Ca va ve le, ca va ve le oh
Ca va ve le oh, ca va ve le oh
(Ca va-ve le)
Ca va ve le, ca va ve le oh (uh-uh, uhn)
Ca va ve le oh, ca va ve le oh

Songtext kommentieren

Log dich ein um einen Eintrag zu schreiben.
Schreibe den ersten Kommentar!

Beliebte Songtexte
von Asake

Fans

»Mogbe« gefällt bisher niemandem.