Songtexte.com Drucklogo

Awodi Songtext
von Asake

Awodi Songtext

(Ọlọlade mi, Àṣàkẹ)
(Tune in to the king of sounds and blues)

Àwòdì fo lókè, o fẹ d′Olùwà
Ẹribi, ẹribi, I wonder oo
Wonder shall never end (wonder) like Pasuma, I wonder
I wonder, Americana wonder oo
Kíní reason? Kíní plan? Kíní scope? Why the beefing?

Catfish lórí títí
Jẹ bí chicken, ṣọbọleyọke jú killing (killing)
Iwájú gán o easy, ẹhìn o ṣé lọ, ọmọ ìyá mí, ṣo tí rísìnyí (rísìnyí)
My ship never sinking, mó kanaku, mó jiggy
They wanna know what I'm thinking

Many, many things, I no fit ṣàlàyé o
2022, mó gbé wọn trabayé o
Olùwà ló gbé from the slum to the top
Èmí kọ, àwọn kọ, wọn o lé t′Ọlọrun
Ìṣù jọba lórí ìyàn
Kémí má ní ìjọba òṣìkà


Òjo l'ọkọ àgbàdo
As e dey go, jásí, my nigga
Aroma ńjo gẹ́, aroma ńle wọn
Aroma ńdé bẹ, fabẹ yá o
Mó ge wọn bí Babayaro
Akabi Kaola, óyà, kabi lórí àwá o

Àwòdì fo lókè, o fẹ d'Olùwà
Ẹribi, ẹribi, I wonder oo
Wonder shall never end (wonder) like Pasuma, I wonder (′der)
I wonder, Americana wonder oo
Kíní reason? Kíní plan? Kíní scope? Why the beefing?

Catfish lórí títí
Jẹ bí chicken, ṣọbọleyọke jú killing (killing)
Iwájú gán o easy, ẹhìn o ṣé lọ, ọmọ ìyá mí, ṣo tí rísìnyí (rísìnyí)
My ship never sinking, mó kanaku, mó jiggy
They wanna know what I′m thinking

They wanna know (aroma re o)
They wanna know (aroma re o)
Aroma ńjo gẹ, aroma ńle wọn
Aroma ńde bẹ fàbẹ yá o
Mó ge wọn bí Babayaro
Akabi Kaola, ó yà, kabi lórí àwá o

Songtext kommentieren

Log dich ein um einen Eintrag zu schreiben.
Schreibe den ersten Kommentar!

Beliebte Songtexte
von Asake

Quiz
„Grenade“ ist von welchem Künstler?

Fans

»Awodi« gefällt bisher niemandem.