Songtexte.com Drucklogo

2:30 Songtext
von Asake

2:30 Songtext

(Ob′, Obah)
(What dem-a say?)
(Obah)
(Rock)
(Ọlọlade mi, Àṣàkẹ)

Àwa dé, àwa dé-dé
Àwa l'ọmọ tọ ń sọ, ti o seke, ye
Orímọlade gbe mi de′bẹ
Jigan, jigan, ẹsẹ mi o de'lẹ, de'lẹ
Àlàyé mi, stop ṣe bẹ
O fẹ jẹ ń bi, o tún fẹ jẹ ń bẹ, ò pọ, sẹ
Agba-awo, f′ẹnu fo fence, sún s′ẹhìn
Àmọ 'rawa, ṣ′o get?


Abínibí yàtọ sí ability
Ẹ sọ̀ fún wọn t'oba tẹ′ri si, wọn má pa l'órí
T′ẹnu kọ, emi promising
Awọn tẹ fọ fun, fọ fun mi
Torí ko s'ẹlòmíì, many men fẹ dàbí mí, ẹ ri bi
Ẹ gbé Ọlọrun tóbi
Mo d'aṣọ ẹbi for my country
You can call me Mr. Money

Mm-mm-mm, mm-mm
2:30 fẹ lu, oya, ka turn up, ki′lẹ to mọ
Mm-mm-mm, mm-mm (ye-ye, ye)
2:30 fẹ lu (2:30 fẹ lu), oya, ka turn up, ki′lẹ to mọ

Èrè mò bawa, ko si ija
Ṣòkòtò penpen, ye, àyé ni'ka
Yebo, yeba
Formulation lo gba, yeja
Ọmọ iyami, ko stay wise
Tranquillity, tranquillity
I no get time to dey form activity
Ko le kalas, I dey find stability


Like Abacha, money long, infinity
What′s the chances, what's the probability
To see a better version of me with agility?
No, you can′t fake reality
Ogun principalities and calamity
Mo ti lọ, mo ti pá 'yẹn ti
Bẹbẹ no dey for Jiji, o ṣí wa ń títí
Still get money like Fiti
Drippin′ like Fiji, I be real G

Mm-mm-mm, mm-mm
2:30 fẹ lu, oya, ka turn up, ki'lẹ to mọ
Mm-mm-mm, mm-mm
2:30 fẹ lu, oya, ka turn up, ki'lẹ to mọ

Songtext kommentieren

Log dich ein um einen Eintrag zu schreiben.
Schreibe den ersten Kommentar!

Beliebte Songtexte
von Asake

Quiz
Welcher Song kommt von Passenger?

Fans

»2:30« gefällt bisher niemandem.